3112 Yoruba - Nigeria
Ise Awon Aposteli 8:30-38
30. Filippi si sure lo, o gbó, o nká iwe woli Isaiah, o si bi i pe, Ohun ti io nká ni, o yé o ?
31. O si dahùn wipe, Yio ha se yè mi, bikoepe nikan tó mi si ona? O sa bè Filippi kio goke wá, ki o si ba on joko.
32. Ibi iwe-mimó ti o si nkà na li ryi, A fà a bi agutan lo fun pipa; ati bi odo-agutan iti tyadi niwaju olurrun ré, béni kó yá nu rè:
33. Ni irsil ré a mu idajo kuro: tani yio sòro iran re ? Nitori a gbà emi rè kuro li aiye.
34. Iwefa si da Filippi lohùn, o ni, Mo bè o, ti tani woli na so òro yi ? Ti ara rè, tabi ti elomiran ?
35. Filippi si yà nu rè, o si bère lati ibi iwe-mimó yi, o sa wasu Jesu fun u.
36. Bi nwon si ti nio li òna, nwon de thi omi kan; iwefa na si wipe, Wò o, omi niyi; kili o dá mi duro lati baptisi ?
37. Filippi si wipe, Bi iwo ba gbagbó tokàntokan, a le baptisi r. O si dahùn o ni, Mo gbagbó pe Jesu Kristi, Omo Olorun ni.
38. O si pa ki kké duro j: awon mejeji si sokal lo sinu omi, ati Filipi ati iwefa; o si baptisi rè
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment