Showing posts with label Yoruba Bible study. Show all posts
Showing posts with label Yoruba Bible study. Show all posts

Saturday, May 3, 2008

Yio ha se yé mi, bikosepenikan tó mi si ona ?

3112 Yoruba - Nigeria

Ise Awon Aposteli 8:30-38

30. Filippi si sure lo, o gbó, o nká iwe woli Isaiah, o si bi i pe, Ohun ti io nká ni, o yé o ?
31. O si dahùn wipe, Yio ha se yè mi, biko��epe �nikan tó mi si ona? O sa bè Filippi kio goke wá, ki o si ba on joko.
32. Ibi iwe-mimó ti o si nkà na li ryi, A fà a bi agutan lo fun pipa; ati bi odo-agutan iti tyadi niwaju olur�run ré, béni kó yá �nu rè:
33. Ni ir�sil� ré a mu idajo kuro: tani yio sòro iran re ? Nitori a gbà emi rè kuro li aiye.
34. Iwefa si da Filippi lohùn, o ni, Mo bè o, ti tani woli na so òro yi ? Ti ara rè, tabi ti elomiran ?
35. Filippi si yà �nu rè, o si bère lati ibi iwe-mimó yi, o sa wasu Jesu fun u.
36. Bi nwon si ti nio li òna, nwon de thi omi kan; iwefa na si wipe, Wò o, omi niyi; kili o dá mi duro lati baptisi ?
37. Filippi si wipe, Bi iwo ba gbagbó tokàntokan, a le baptisi r�. O si dahùn o ni, Mo gbagbó pe Jesu Kristi, Omo Olorun ni.
38. O si pa�� ki k�ké duro j�: awon mejeji si sokal� lo sinu omi, ati Filipi ati iwefa; o si baptisi rè